Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hag 2:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi ẹnikan ba rù ẹran mimọ́ ni iṣẹti aṣọ rẹ̀, ti o si fi iṣẹti aṣọ rẹ̀ kan àkara, tabi àṣaró, tabi ọti-waini, tabi ororo, tabi ẹrankẹran, yio ha jẹ mimọ́? Awọn alufa si dahùn wipe, Bẹ̃kọ.

Ka pipe ipin Hag 2

Wo Hag 2:12 ni o tọ