Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Est 9:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn Ju lanà rẹ̀, nwọn si gbà a kanri wọn, ati fun iru-ọmọ wọn, ati fun gbogbo awọn ti o dà ara wọn pọ̀ mọ wọn, pe ki o máṣe yẹ̀, ki nwọn ki o ma pa ọjọ mejeji wọnyi mọ́ gẹgẹ bi ikọwe wọn, ati gẹgẹ bi akokò wọn ti a yàn lọdọdun.

Ka pipe ipin Est 9

Wo Est 9:27 ni o tọ