Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 9:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni igba ẹbọ aṣalẹ ni mo si dide kuro ninu ikãnu mi; pẹlu aṣọ ati agbáda mi yiya, mo si wolẹ lori ẽkun mi, mo si nà ọwọ mi si Oluwa Ọlọrun mi.

Ka pipe ipin Esr 9

Wo Esr 9:5 ni o tọ