Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 9:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati lẹhin gbogbo eyi ti o de si wa nitori iṣe buburu wa, ati nitori ẹbi wa nla, nitoripe iwọ Ọlọrun wa ti dá wa si ju bi o ti yẹ lọ fun aiṣedede wa, o si fi iru igbala bi eyi fun wa;

Ka pipe ipin Esr 9

Wo Esr 9:13 ni o tọ