Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 9:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ti iwọ ti pa lati ẹnu awọn woli iranṣẹ rẹ wá, wipe, Ilẹ na ti ẹnyin nlọ igbà nì, ilẹ alaimọ́ ni, fun ẹgbin awọn enia ilẹ na, fun irira wọn, pẹlu ìwa-ẽri ti nwọn fi kun lati ikangun kan de ekeji.

Ka pipe ipin Esr 9

Wo Esr 9:11 ni o tọ