Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 7:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati iwọ, Esra, gẹgẹ bi ọgbọ́n Ọlọrun rẹ ti o wà li ọwọ rẹ, yan awọn oloyè ati onidajọ, ti nwọn o ma da ẹjọ fun gbogbo awọn enia ti o wà li oke-odò, gbogbo iru awọn ti o mọ̀ ofin Ọlọrun rẹ, ki ẹnyin ki o si ma kọ́ awọn ti kò mọ̀ wọn.

Ka pipe ipin Esr 7

Wo Esr 7:25 ni o tọ