Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 7:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Pẹlupẹlu ki ẹnyin ki o mọ̀ dajudaju pe, ẹnyin kò ni oyè lati di owo-ori, owo-odè, ati owo-bodè ru gbogbo awọn alufa, ati awọn ọmọ Lefi, awọn akọrin, awọn adèna, awọn Netinimu, ati awọn iranṣẹ ninu ile Ọlọrun yi,

Ka pipe ipin Esr 7

Wo Esr 7:24 ni o tọ