Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 5:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Li akoko na ni Serubbabeli ọmọ Ṣealtieli, ati Jeṣua ọmọ Josadaki dide, nwọn si bẹ̀rẹ si ikọ́ ile Ọlọrun ni Jerusalemu; awọn woli Ọlọrun si wà pẹlu wọn ti nràn wọn lọwọ.

Ka pipe ipin Esr 5

Wo Esr 5:2 ni o tọ