Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 5:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

ṢUGBỌN awọn woli, Haggai woli, ati Sekariah ọmọ Iddo, sọ asọtẹlẹ fun awọn Ju ti o wà ni Juda ati Jerusalemu li orukọ Ọlọrun Israeli.

Ka pipe ipin Esr 5

Wo Esr 5:1 ni o tọ