Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 9:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Oluwa si wi fun u pe, La ãrin ilu já, li ãrin Jerusalemu, ki o si sami si iwaju awọn ọkunrin ti nkẹdùn, ti nwọn si nkigbe nitori ohun irira ti nwọn nṣe lãrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 9

Wo Esek 9:4 ni o tọ