Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 9:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ogo Ọlọrun Israeli si ti goke kuro lori kerubu, eyi ti o ti wà, si iloro ile. O si pe ọkunrin na ti o wọ aṣọ ọgbọ̀, ti o ni ìwo-tàdawa akọwe li ẹgbẹ́ rẹ̀:

Ka pipe ipin Esek 9

Wo Esek 9:3 ni o tọ