Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 8:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o wi fun mi pe, Iwọ ri eyi, ọmọ enia? ohun kekere ni fun ile Juda lati ṣe ohun irira ti nwọn nṣe nihin? nitori nwọn fi ìwa-ipa kún ilẹ na, nwọn si ti pada lati mu mi binu, si kiye si i, nwọn tẹ̀ ẹka-igi bọ imú wọn.

Ka pipe ipin Esek 8

Wo Esek 8:17 ni o tọ