Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 48:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati fun wọn, ani fun awọn alufa, ni ọrẹ mimọ́ yi yio jẹ; ni ihà ariwa, ẹgbã-mejila, o le ẹgbẹrun ni gigùn, ati ni ihà iwọ-õrun, ẹgbã-marun ni ibú, ati ni ihà ila-õrun, ẹgbã-marun ni ibú, ati ni ihà gusu, ẹgbã-mejila, o le ẹgbẹrun ni gigùn: ibi mimọ́ yio si wà lãrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 48

Wo Esek 48:10 ni o tọ