Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 47:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ni ihà ila-õrun ẹ o wọ̀n lati ãrin Haurani, ati lati ãrin Damasku, ati lati ãrin Gileadi, ati lati ãrin ilẹ Israeli lẹba Jordani, lati ãlà titi de okun ila-õrun. Eyi ni ihà ila-õrun.

Ka pipe ipin Esek 47

Wo Esek 47:18 ni o tọ