Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 44:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati nwọn ba si lọ si agbalá ode, ani si agbalá ode sọdọ awọn enia, nwọn o bọ́ ẹ̀wu wọn ti wọn ifi ṣe iranṣẹ, nwọn o si fi wọn si awọn yará mimọ́, nwọn o si wọ̀ ẹ̀wu miran; nwọn kì yio si fi ẹ̀wu wọn sọ awọn enia di mimọ́.

Ka pipe ipin Esek 44

Wo Esek 44:19 ni o tọ