Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 44:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si ni filà ọ̀gbọ li ori wọn, ṣòkoto ọ̀gbọ ni nwọn o si wọ̀ ni idí wọn; nwọn kì o si fi ohun ti imuni lãgùn dì amurè.

Ka pipe ipin Esek 44

Wo Esek 44:18 ni o tọ