Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 43:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ni titẹ́ iloro wọn nibi iloro mi, ati opó wọn nibi opó mi, ogiri si wà lãrin emi ati awọn, nwọn si ti ba orukọ mimọ́ mi jẹ nipa ohun irira wọn ti nwọn ti ṣe: mo si run wọn ni ibinu mi.

Ka pipe ipin Esek 43

Wo Esek 43:8 ni o tọ