Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 43:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si wi fun mi pe, Ọmọ enia, ibi itẹ mi, ati ibi atẹlẹṣẹ mi, nibiti emi o gbe lãrin awọn ọmọ Israeli lailai, ati orukọ mimọ́ mi, ni ki ile Israeli má bajẹ mọ, awọn, tabi ọba wọn, nipa panṣaga wọn, tabi nipa okú ọba wọn ni ibi giga wọn.

Ka pipe ipin Esek 43

Wo Esek 43:7 ni o tọ