Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 43:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si dabi irí iran ti mo ri, gẹgẹ bi iran ti mo ri nigbati mo wá lati pa ilu na run: iran na si dabi iran ti mo ri lẹba odò Kebari, mo si doju mi bolẹ.

Ka pipe ipin Esek 43

Wo Esek 43:3 ni o tọ