Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 43:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si kiyesi i, ogo Ọlọrun Israeli wá lati ọ̀na ila-õrun: ati ohùn rẹ̀ ri bi ariwo omi pupọ̀: aiye si ràn fun ogo rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 43

Wo Esek 43:2 ni o tọ