Awọn ilẹkùn mejeji na ni awẹ, awẹ meji ti nyi; awẹ meji fun ilẹkùn kan, ati awẹ meji fun ilẹkùn keji.