Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 40:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati fèrese wọn, ati iloro wọn, ati igi ọpẹ wọn jẹ gẹgẹ bi ìwọn ti ẹnu-ọ̀na ti o kọju si ọ̀na ila-õrun; nwọn si ba atẹgun meje gùn oke rẹ̀ lọ; awọn iloro na si mbẹ niwaju wọn.

Ka pipe ipin Esek 40

Wo Esek 40:22 ni o tọ