Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 40:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn yará kékèké ibẹ̀ jẹ mẹta niha ìhin, mẹta nihà ọhun; awọn atẹrigba ibẹ ati iloro ibẹ jẹ gẹgẹ bi ìwọn ẹnu-ọ̀na ekini: gigùn rẹ̀ jẹ ãdọta igbọnwọ, ibú rẹ̀ si jẹ igbọnwọ mẹ̃dọgbọ̀n.

Ka pipe ipin Esek 40

Wo Esek 40:21 ni o tọ