Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 40:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si mu mi wá si agbala ode, si kiyesi i, ọ̀pọlọpọ yará mbẹ nibẹ, a si fi okuta tẹ́ agbala na niha gbogbo: ọgbọ̀n yará ni mbẹ lori okuta itẹlẹ na.

Ka pipe ipin Esek 40

Wo Esek 40:17 ni o tọ