Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 40:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ferese tõro si mbẹ lara yará kékèké na, ati lara atẹrigba wọn ninu ẹnu-ọ̀na niha gbogbo ati pẹlu yará iloro: ferese pupọ si mbẹ niha inu gbogbo: igi ọpẹ si mbẹ lara olukuluku atẹrigbà.

Ka pipe ipin Esek 40

Wo Esek 40:16 ni o tọ