Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 33:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati emi o wi fun olododo pe, yiyè ni yio yè, bi o ba gbẹkẹle ododo ara rẹ̀, ti o si ṣe aiṣedẽde, gbogbo ododo rẹ̀ li a kì yio ranti mọ, ṣugbọn nitori aiṣedẽde ti o ti ṣe, on o ti itori rẹ̀ kú.

Ka pipe ipin Esek 33

Wo Esek 33:13 ni o tọ