Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 3:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn bi iwọ ba kilọ̀ fun enia buburu, ti kò si kuro ninu buburu rẹ̀, ti ko yipada kuro li ọ̀na buburu rẹ̀, yio kú ninu ẹ̀ṣẹ rẹ̀, ṣugbọn ọrun rẹ mọ́.

Ka pipe ipin Esek 3

Wo Esek 3:19 ni o tọ