Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 29:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo ti fi ilẹ Egipti fun u, fun irú ti o sìn si i, nitoriti nwọn ṣiṣẹ́ fun mi, li Oluwa Ọlọrun wi.

Ka pipe ipin Esek 29

Wo Esek 29:20 ni o tọ