Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 29:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Kiyesi i, emi o fi ilẹ Egipti fun Nebukadresari ọba Babiloni; yio si kó awọn ọ̀pọlọpọ enia rẹ̀, ati ikógun rẹ̀, ati ijẹ rẹ̀; yio si jẹ owo ọ̀ya fun awọn ogun rẹ̀.

Ka pipe ipin Esek 29

Wo Esek 29:19 ni o tọ