Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 26:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati emi o bá mu ọ walẹ pẹlu awọn ti o sọkalẹ sinu ihò, pẹlu awọn enia igbãni, ti emi o si gbe ọ kà ibi isalẹ ilẹ aiye, ni ibi ahoro igbãni, pẹlu awọn ti o sọkalẹ lọ si ihò, ki a máṣe gbe inu rẹ mọ́: emi o si gbe ogo kalẹ ni ilẹ awọn alãye;

Ka pipe ipin Esek 26

Wo Esek 26:20 ni o tọ