Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 26:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Nigbati emi o sọ ọ di ahoro ilu, gẹgẹ bi ilu wọnni ti a kò gbe inu wọn; nigbati emi o si mu ibú wá sori rẹ, ati omi nla yio si bò ọ.

Ka pipe ipin Esek 26

Wo Esek 26:19 ni o tọ