Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 20:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nwọn ṣọ̀tẹ si mi, nwọn kò si fẹ fi eti si mi: olukuluku wọn kò gbe ohun-irira oju wọn junù, bẹ̃ni nwọn kò kọ oriṣa Egipti silẹ: nigbana ni mo wipe, emi o da irúnu mi si wọn lori, lati pari ibinu mi si wọn lãrin ilẹ Egipti.

Ka pipe ipin Esek 20

Wo Esek 20:8 ni o tọ