Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 20:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Mo si wi fun wọn pe, Ki olukuluku ninu nyin gbe irira oju rẹ̀ junù, ẹ má si ṣe fi oriṣa Egipti sọ ara nyin di aimọ́: emi ni Oluwa Ọlọrun nyin.

Ka pipe ipin Esek 20

Wo Esek 20:7 ni o tọ