Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 20:40 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori lori oke mimọ́ mi, lori oke giga Israeli, ni Oluwa Ọlọrun wi, nibẹ ni gbogbo ile Israeli, gbogbo wọn ni ilẹ na, yio sìn mi: nibẹ ni emi o gbà wọn, nibẹ ni emi o si bere ẹbọ nyin, ati ọrẹ akọso nyin, pẹlu ohun mimọ́ nyin.

Ka pipe ipin Esek 20

Wo Esek 20:40 ni o tọ