Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 20:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi o ṣe ti nyin, ile Israeli, Bayi ni Oluwa Ọlọrun wi, Ẹ lọ, olukuluku sìn oriṣa rẹ̀, ati lẹhin eyi pẹlu, bi ẹnyin kì yio ba fi eti si mi: ṣugbọn ẹ máṣe fi ẹ̀bun nyin ati oriṣa nyin bà orukọ mimọ́ mi jẹ́ mọ.

Ka pipe ipin Esek 20

Wo Esek 20:39 ni o tọ