Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 17:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi o si nà àwọn mi si i lori, a o si mu u ninu ẹgẹ́ mi; emi o si mu u de Babiloni, emi o si ba a rojọ nibẹ, nitori ẹ̀ṣẹ ti o ti da si mi.

Ka pipe ipin Esek 17

Wo Esek 17:20 ni o tọ