Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:55 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati awọn arabinrin rẹ Sodomu, ati awọn ọmọ rẹ̀ obinrin, ba pada si ipò wọn iṣaju, ti Samaria ati awọn ọmọ rẹ̀ obinrin ba pada si ipò wọn iṣaju, nigbana ni iwọ ati awọn ọmọ rẹ obinrin yio pada si ipò nyin iṣaju.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:55 ni o tọ