Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ ni ọmọ iyá rẹ ti o kọ̀ ọkọ rẹ̀, ati awọn ọmọ rẹ̀; iwọ ni arabinrin awọn arabinrin rẹ, ti o kọ̀ awọn ọkọ wọn ati awọn ọmọ wọn: ará Hiti ni iyá rẹ, ará Amori si ni baba rẹ.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:45 ni o tọ