Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ni gbogbo ohun irira rẹ, ati panṣaga rẹ, iwọ kò ranti ọjọ ewe rẹ, nigbati iwọ wà nihoho ti o si wà goloto, ti a si bà ọ jẹ ninu ẹjẹ rẹ.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:22 ni o tọ