Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 11:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina wipe, Bayi li Oluwa Ọlọrun wi, Bi mo tilẹ ti tá wọn nù réré lãrin awọn keferi; bi mo si ti tú wọn ka lãrin ilẹ pupọ, sibẹ emi o jẹ ibi mimọ́ kekere fun wọn ni ilẹ ti wọn o de.

Ka pipe ipin Esek 11

Wo Esek 11:16 ni o tọ