Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 11:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọmọ enia, awọn ará rẹ, ani awọn ará rẹ, awọn ọkunrin ninu ibatan rẹ, ati gbogbo ile Israeli patapata, ni awọn ti awọn ara Jerusalemu ti wi fun pe, Ẹ jina si Oluwa; awa ni a fi ilẹ yi fun ni ini.

Ka pipe ipin Esek 11

Wo Esek 11:15 ni o tọ