Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 4:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe, bi nwọn kò ba si gbà àmi mejeji yi gbọ́ pẹlu, ti nwọn kò si fetisi ohùn rẹ, njẹ ki iwọ ki o bù ninu omi odò nì, ki o si dà a si iyangbẹ ilẹ: omi na ti iwọ bù ninu odò yio di ẹ̀jẹ ni iyangbẹ ilẹ.

Ka pipe ipin Eks 4

Wo Eks 4:9 ni o tọ