Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 35:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Olukuluku ẹniti o ta ọrẹ fadakà ati idẹ, o mú ọrẹ OLUWA wá: ati olukuluku enia lati ọdọ ẹniti a ri igi ṣittimu fun iṣẹkiṣẹ ìsin na, mú u wá.

Ka pipe ipin Eks 35

Wo Eks 35:24 ni o tọ