Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 35:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati olukuluku enia lọdọ ẹniti a ri aṣọ-alaró, ati elesè àluko, ati ododó, ati ọ̀gbọ daradara, ati irun ewurẹ, ati awọ àgbo pupa, ati awọ seali, mú wọn wá.

Ka pipe ipin Eks 35

Wo Eks 35:23 ni o tọ