Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 34:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iwọ kò gbọdọ ta ẹ̀jẹ ẹbọ mi silẹ nibiti iwukàra wà, bẹ̃li ẹbọ ajọ irekọja kò gbọdọ kù titi di owurọ̀.

Ka pipe ipin Eks 34

Wo Eks 34:25 ni o tọ