Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 34:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ijọ́ mẹfa ni ki iwọ ki o ṣe iṣẹ́, ṣugbọn ni ijọ́ keje ni ki iwọ ki o simi: ni ìgba ifunrugbìn, ati ni ìgba ikore ni ki iwọ ki o simi.

Ka pipe ipin Eks 34

Wo Eks 34:21 ni o tọ