Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 34:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn akọ́bi kẹtẹkẹtẹ ni ki iwọ ki o fi ọdọ-agutan rapada: bi iwọ kò ba si rà a pada, njẹ ki iwọ ki o ṣẹ́ ẹ li ọrùn. Gbogbo akọ́bi ninu awọn ọmọkunrin rẹ ni ki iwọ ki o rapada. Kò si sí ẹnikan ti yio farahàn niwaju mi lọwọ ofo.

Ka pipe ipin Eks 34

Wo Eks 34:20 ni o tọ