Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 3:17 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi si ti wipe, Emi o mú nyin goke jade ninu ipọnju Egipti si ilẹ awọn ara Kenaani, ati ti awọn Hitti, ati ti awọn Amori, ati ti awọn Perissi, ati ti awọn Hifi, ati ti awọn Jebusi, si ilẹ ti nṣàn fun wàra ati fun oyin.

Ka pipe ipin Eks 3

Wo Eks 3:17 ni o tọ