Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 3:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lọ, ki o si kó awọn àgba Israeli jọ, ki o si wi fun wọn pe, OLUWA, Ọlọrun awọn baba nyin, Ọlọrun Abrahamu, ti Isaaki, ati ti Jakobu, li o farahàn mi wipe, Lõtọ ni mo ti bẹ̀ nyin wò, mo si ti ri ohun ti a nṣe si nyin ni Egipti:

Ka pipe ipin Eks 3

Wo Eks 3:16 ni o tọ