Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Eks 23:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti angeli mi yio ṣaju rẹ, yio si mú ọ dé ọdọ awọn enia Amori, ati awọn Hitti, ati awọn Perissi, ati awọn ara Kenaani, awọn Hifi, ati awọn Jebusi: emi a si ke wọn kuro.

Ka pipe ipin Eks 23

Wo Eks 23:23 ni o tọ